10 Ó tún sọ pé,“Ní àtètèkọ́ṣe, ìwọ Olúwa, ìwọ fi ìdí ayé sọlẹ̀,àwọn ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ ara rẹ.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 1
Wo Àwọn Hébérù 1:10 ni o tọ