Àwọn Hébérù 10:26 BMY

26 Nítorí bí àwa ba mọ̀ọ́mọ̀ dẹ́sẹ̀ lẹ̀yìn ìgbà tí àwa bá ti gba ìmọ̀ òtítọ́ kò tún sí ẹbọ fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 10

Wo Àwọn Hébérù 10:26 ni o tọ