Àwọn Hébérù 10:8 BMY

8 Nígbà tí o wí ni ìṣáajú pé, “Ìwọ kò fẹ́ ẹbọ àti ọ̀rẹ àti ẹbọ sísun, àti ẹbọ fún ẹ̀ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò ni inú dídùn si wọn” (àwọn èyí tí a ń rú gẹ́gẹ́ bí òfin).

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 10

Wo Àwọn Hébérù 10:8 ni o tọ