Àwọn Hébérù 11:26 BMY

26 Ó ka ẹ̀gàn Kírísítì si ọrọ̀ tí ó pọ̀jù àwọn ìṣúrà Éjípítì lọ: Nítorí tí ó ń wo èrè náà.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:26 ni o tọ