34 Tí wọn pa agbára iná, ti wọn bọ́ lọ́wọ́ ojú idà, tí a sọ di alágbára nínú àìlera, ti wọn dí akọni ni ìjà, wọn lé ogun àwọn àjèjì sá.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11
Wo Àwọn Hébérù 11:34 ni o tọ