10 Nítorí wọ́n tọ́ wa fún ọjọ́ díẹ̀ bí o ba ti dára lójú wọn; ṣùgbọ́n òun (tọ́ wa) fún èrè wa, kí àwa lè ṣe alábápín ìwà mímọ́ rẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12
Wo Àwọn Hébérù 12:10 ni o tọ