Àwọn Hébérù 12:20 BMY

20 Nítorí pé ara wọn kò lè gba ohun tí ó palaṣẹ, “Bí o tilẹ̀ jẹ ẹranko ni o farakan òkè náà, a o sọ ọ ni òkúta, tàbí a o gun un ní ọ̀kọ̀ pa.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12

Wo Àwọn Hébérù 12:20 ni o tọ