Àwọn Hébérù 12:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin wá sí òkè Síónì, àti sí ìlú Ọlọ́run alààyè, ti Jerúsálémù ti ọ̀run, àti si ẹgbẹ́ àwọn áńgẹ́lì àìníye,

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12

Wo Àwọn Hébérù 12:22 ni o tọ