Àwọn Hébérù 12:8 BMY

8 Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin ba wà láìsí ìbáwí, nínú èyí tí gbogbo ènìyàn ti jẹ alábápín, njẹ́ ọmọ àlè ni yín, ẹ kì í sì ṣe ọmọ.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12

Wo Àwọn Hébérù 12:8 ni o tọ