23 Ẹ mọ pé a sá Timótéù arákùnrin wa sílẹ̀; bí ó ba tètè dé, èmí pẹ̀lú rẹ̀ yóò rí yín, àti gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13
Wo Àwọn Hébérù 13:23 ni o tọ