Àwọn Hébérù 2:13 BMY

13 Àti pẹ̀lú,“Èmi yóò gbẹ́kẹ̀ mi lé e.”Àti pẹ̀lú,“Kíyèsi í, èmi rèé, èmi àti àwọn ọmọ tí Ọlọ́run fi fún mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 2

Wo Àwọn Hébérù 2:13 ni o tọ