Àwọn Hébérù 2:5 BMY

5 Nítórí pé, kì í ṣe abẹ́ ìsàkóso àwọn ańgẹ́lì ni ó fi ayé tí ń bọ̀, tí àwa ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ sí.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 2

Wo Àwọn Hébérù 2:5 ni o tọ