13 Kò sí ẹ̀dá kan tí kò farahàn níwájú rẹ̀, ṣùgbọ́n ohun gbogbo ni ó wà níhòòhò tí a sì ṣípayá fún ojú rẹ̀, níwájú ẹni tí àwa yóò jíyìn.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4
Wo Àwọn Hébérù 4:13 ni o tọ