Àwọn Hébérù 4:4 BMY

4 Nítorí ó ti sọ níbìkan ní ti ọjọ́ kéje bayìí pé, “Ọlọ́run sì sinmi ní ọjọ́ keje kúrò nínú iṣẹ́ rẹ̀ gbogbo.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:4 ni o tọ