Àwọn Hébérù 5:4 BMY

4 Ko sí ẹni tí o gba ọlá yìí fún ara rẹ̀, bí kò se ẹni tí a pè láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá gẹ́gẹ́ bí a ti pe Árọ́nì.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 5

Wo Àwọn Hébérù 5:4 ni o tọ