Àwọn Hébérù 5:8 BMY

8 Bí òun tilẹ̀ ń ṣe Ọmọ Ọlọ́run, síbẹ̀ ó kọ́ gbọ́ràn nípa ohun tí ó jìyà rẹ̀;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 5

Wo Àwọn Hébérù 5:8 ni o tọ