Àwọn Hébérù 6:17 BMY

17 Nínú èyí tí Ọlọ́run, ẹni tí ń fẹ́ gidgidi láti fi àìlèyípadà ète rẹ̀ hàn fún àwọn ajogún ìlérí náà, ó fi ìbúra sáàrin wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 6

Wo Àwọn Hébérù 6:17 ni o tọ