11 Olúkúlùkù kò ní tún máa kọ́ ara ìlú rẹ̀,tàbi olukulùkù arákùnrin rẹ̀, pé, ‘mọ Olúwa,’Nítorí pé gbogbo wọn ni yóò mọ̀ mí,láti kékere dé àgbà.
Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8
Wo Àwọn Hébérù 8:11 ni o tọ