Àwọn Hébérù 8:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí o ti gba iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí ó ni ọlá jù, níwọ̀n bí o ti jẹ pé alárinà májẹ̀mú tí o dára jù ní i ṣe, èyí tí a fi ṣe òfin lórí ìlérí tí o sàn jù bẹ́ẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8

Wo Àwọn Hébérù 8:6 ni o tọ