Àwọn Hébérù 8:9 BMY

9 Kì í ṣe gẹ́gẹ́ bí májẹ̀mútí mo ti bá àwọn baba baba wọn dá,nígbà tí mo fà wọ́n lọ́wọ́ láti mú wọn jádekúrò ní Íjíbítì, nítorí wọn kò jẹ́ olótítọ́ sí májẹ̀mú mièmi kò sì ta wọ́n nu, ni Olúwa wíni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8

Wo Àwọn Hébérù 8:9 ni o tọ