Àwọn Hébérù 9:2 BMY

2 A gbé agọ́ kan dìde. Nínú yàrá rẹ̀ àkọ́kọ́ ni a ti rí ọ̀pá fìtílà, tábìlì, àti àkàrà ìfihàn. Èyí tí a ń pè ní ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:2 ni o tọ