Àwọn Hébérù 9:6 BMY

6 Ǹjẹ́ nígbà tí a ti ṣe ètò nǹkan wọ̀nyí báyìí, àwọn àlùfáà a máa lọ nígbàkúgbà sínú àgọ́ èkínní, wọn a máa ṣe iṣẹ́ ìsìn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:6 ni o tọ