Jákọ́bù 3:12 BMY

12 Ẹ̀yin ará mi, igi ọ̀pọ̀tọ́ ha le so èso ólífì bí? Tàbí àjàrà ha lè so èso ọ̀pọ̀tọ́? Bẹ́ẹ̀ ni orísun kan kò le sun omíró àti omi tútù.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:12 ni o tọ