Jákọ́bù 3:13 BMY

13 Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:13 ni o tọ