Jákọ́bù 3:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin bá ní owú kíkorò àti ìjà ní ọkàn yín, ẹ má ṣe ṣe féfé, ẹ má sì ṣèké sí òtítọ́.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:14 ni o tọ