Jákọ́bù 3:15 BMY

15 Ọgbọ́n yìí kì í ṣe èyí tí ó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá, ṣùgbọ́n ti ayé ni, ti ara ni, ti ẹ̀mí èṣù ni.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 3

Wo Jákọ́bù 3:15 ni o tọ