Amosi 3:11 BM

11 Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní: “Ọ̀tá yóo yí ilẹ̀ náà po, wọn yóo wó ibi ààbò yín, wọn yóo sì kó ìṣúra tí ó wà ní àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.”

Ka pipe ipin Amosi 3

Wo Amosi 3:11 ni o tọ