Amosi 3:6 BM

6 “Ṣé eniyan lè fọn fèrè ogun láàrin ìlú kí àyà ará ìlú má já?“Àbí nǹkan ibi lè ṣẹlẹ̀ ní ìlú láìṣe pé OLUWA ni ó ṣe é?

Ka pipe ipin Amosi 3

Wo Amosi 3:6 ni o tọ