Amosi 3:8 BM

8 “Kinniun bú ramúramù, ta ni ẹ̀rù kò ní bà?“OLUWA Ọlọrun ti sọ̀rọ̀, ta ló gbọdọ̀ má sọ àsọtẹ́lẹ̀?”

Ka pipe ipin Amosi 3

Wo Amosi 3:8 ni o tọ