Amosi 6:7 BM

7 Nítorí náà, àwọn ni wọn yóo kọ́kọ́ lọ sí ìgbèkùn, gbogbo àsè ati ayẹyẹ àwọn tí wọn ń nà kalẹ̀ sórí ibùsùn yóo dópin.

Ka pipe ipin Amosi 6

Wo Amosi 6:7 ni o tọ