Daniẹli 6:27 BM

27 Ó ń gbani là,ó ń dáni nídè.Ó ń ṣiṣẹ́ àánú tí ó yani lẹ́nu ní ọ̀run ati ní ayé.Òun ni ó gba Daniẹli lọ́wọ́ agbára kinniun.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:27 ni o tọ