Daniẹli 7:1 BM

1 Ní ọdún kinni tí Beṣasari jọba ní Babiloni, Daniẹli lá àlá, o sì rí àwọn ìran kan nígbà tí ó sùn lórí ibùsùn rẹ̀. Ó bá kọ kókó ohun tí ó rí lójú àlá náà sílẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 7

Wo Daniẹli 7:1 ni o tọ