Ẹsira 10:24 BM

24 Ninu àwọn akọrin, Eliaṣibu nìkan ni ó fẹ́ obinrin àjèjì.Orúkọ àwọn aṣọ́nà tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì nìwọ̀nyí:Ṣalumu, Telemu, ati Uri.

Ka pipe ipin Ẹsira 10

Wo Ẹsira 10:24 ni o tọ