Ẹsira 2:68 BM

68 Nígbà tí wọ́n dé ilé OLUWA ní Jerusalẹmu, díẹ̀ ninu àwọn olórí ìdílé náà fi ọrẹ àtinúwá sílẹ̀ láti tún ilé Ọlọrun kọ́ sí ààyè rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsira 2

Wo Ẹsira 2:68 ni o tọ