Ẹsira 4:1 BM

1 Nígbà ti àwọn ọ̀tá Juda ati ti Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn tí wọ́n ti ìgbèkùn dé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé OLUWA Ọlọrun Israẹli,

Ka pipe ipin Ẹsira 4

Wo Ẹsira 4:1 ni o tọ