Ẹsira 6:10 BM

10 Kí wọ́n baà lè rú ẹbọ tí yóo jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà sí Ọlọrun ọ̀run, kí wọ́n sì lè máa gbadura ibukun fún èmi ati àwọn ọmọ mi.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:10 ni o tọ