Ẹsira 6:13 BM

13 Tatenai, gomina, Ṣetari Bosenai ati àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn tẹ̀lé gbogbo àṣẹ tí Dariusi ọba pa fún wọn lẹ́sẹẹsẹ.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:13 ni o tọ