Ẹsira 6:19 BM

19 Ní ọjọ́ kẹrinla, oṣù kinni ọdún tí ó tẹ̀lé e, àwọn Juu tí wọ́n pada láti oko ẹrú ṣe ayẹyẹ Àjọ Ìrékọjá.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:19 ni o tọ