Ẹsira 7:1 BM

1 Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya,

Ka pipe ipin Ẹsira 7

Wo Ẹsira 7:1 ni o tọ