Ẹsira 7:10 BM

10 Nítorí Ẹsira fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sí kíkọ́ òfin OLUWA, ati pípa á mọ́ ati kíkọ́ gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Ẹsira 7

Wo Ẹsira 7:10 ni o tọ