19 Gbogbo ohun èlò tí wọ́n kó fún ọ fún lílò ninu Tẹmpili Ọlọrun ni kí o kó lọ sí Jerusalẹmu, níwájú Ọlọrun.
Ka pipe ipin Ẹsira 7
Wo Ẹsira 7:19 ni o tọ