Ẹsira 8:28 BM

28 Mo sọ fún wọn pé, “A yà yín ati gbogbo nǹkan wọnyi sí mímọ́ fún OLUWA. Fadaka ati wúrà jẹ́ ọrẹ àtinúwá fún OLUWA Ọlọrun àwọn baba yín.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:28 ni o tọ