Ẹsira 8:30 BM

30 Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi gba fadaka, wúrà ati àwọn ohun èlò náà, wọ́n kó wọn wá sinu ilé Ọlọrun wa ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:30 ni o tọ