4 Ninu àwọn ọmọ Pahati Moabu, Eliehoenai, ọmọ Serahaya, ni olórí;orúkọ igba (200) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Ka pipe ipin Ẹsira 8
Wo Ẹsira 8:4 ni o tọ