Hosia 11:9 BM

9 N kò ní fa ibinu yọ mọ́,n kò ní pa Efuraimu run mọ́,nítorí pé Ọlọrun ni mí,n kì í ṣe eniyan,èmi ni Ẹni Mímọ́ tí ó wà láàrin yín,n kò sì ní pa yín run.

Ka pipe ipin Hosia 11

Wo Hosia 11:9 ni o tọ