7 Wọn óo pada sábẹ́ ààbò mi,wọn óo rúwé bí igi inú ọgbà;wọn óo sì tanná bí àjàrà,òórùn wọn óo dàbí ti waini Lẹbanoni.
Ka pipe ipin Hosia 14
Wo Hosia 14:7 ni o tọ