Hosia 2:9 BM

9 Nítorí náà n óo gba waini ati ọkà mi pada ní àkókò wọn, n óo sì gba aṣọ òtútù ati ẹ̀wù fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun mi, tí kì bá fi bo ìhòòhò rẹ̀.

Ka pipe ipin Hosia 2

Wo Hosia 2:9 ni o tọ