Hosia 4:3 BM

3 Nítorí náà, ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀, gbogbo àwọn tí wọn ń gbé ibẹ̀ ń jìyà, àwọn ẹranko, àwọn ẹyẹ, ati àwọn ẹja sì ń ṣègbé.”

Ka pipe ipin Hosia 4

Wo Hosia 4:3 ni o tọ