Hosia 7:3 BM

3 OLUWA wí pé, “Àwọn eniyan ń dá ọba ninu dùn, nípa ìwà ibi wọn, wọ́n ń mú àwọn ìjòyè lóríyá nípa ìwà ẹ̀tàn wọn.

Ka pipe ipin Hosia 7

Wo Hosia 7:3 ni o tọ