Hosia 8:8 BM

8 A ti tú Israẹli ká, wọ́n ti kọ́ àṣàkaṣà àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà láàrin wọn, wọ́n sì dàbí ohun èlò tí kò wúlò.

Ka pipe ipin Hosia 8

Wo Hosia 8:8 ni o tọ